Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) is a Book app by Andrew Blurton. Eleyi jẹ Bibeli ni Yorùbá ni pipe pẹlu gbogbo awọn iwe ohun, orí ati awọn ẹsẹ..
APK (Android Package Kit) files are the raw files of an Android app. Learn how to install bibeli-mimọ-the-bible-in-yoruba.apk file on your phone in 4 Simple Steps:
Yes. We provide some of the safest Apk download mirrors for getting the Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) apk.
1. Eleyi jẹ Bibeli ni Yorùbá ni pipe pẹlu gbogbo awọn iwe ohun, orí ati awọn ẹsẹ.. A ti fi ọpọlọpọ awọn ẹya ohun mere mere lati jẹki kika ati iwadi ti Bibeli re gbẹgẹ.
2. Ni bayi o le fi ẹsẹ lati nu Bibeli han awọn ọrẹ rẹ taara lori Facebook, Twitter tabi nipasẹ Email (ki o si fi erongba ọkan rẹ han).
3. Awọn ‘app’ yi ni o ni "iboju wẹẹrẹ" ti o jẹ ki o sese fun o lati wo ẹsẹ meji ni akoko kan na ati ki o le ka ki o si ṣe afiwe wọn l’ẹgbẹ ara won.
4. Ọpọlọpọ awọn ti nlo ate eto wa n beere fun ohun ti wọn le lo lati le kọ awọn àdúrà wọn, ero tabi oro ti won gba nigbati wọn ba n ka Bibeli wọn.
5. Nibayi o le saami ti o yatọ si awon ẹsẹ bibeli pelu awọn awọ ti o ba wu ọ.
6. O le lo ohun elo iwa’di iṣẹ lati wa ẹsẹ Bibeli lori ero kan pato.
7. A ma n gbọ a si tun mu awọn ohun titun sinu ‘app’ na nipase awon arọwa yin.
8. O le se ifiwe ran se (email) awọn iwe aṣẹ lati nu ‘app’.
9. Kọ rọra tẹ ọrọ ti ohun wa ki ‘app’ si gbe ẹsẹ ti o jẹmọ jade si ọ.
10. Ṣẹda awọn iwe aṣẹ eleyọ tabi olọpọ ẹsẹ.
11. Se afiwe awon ẹsẹ kankan lati nu eda ti Swedish pelu tie de oyibo.
Apk Mirror 1: : Download APK
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|