Arquivos APK (Android Package Kit) são os arquivos brutos de um aplicativo Para Android. Saiba como instalar bibeli-mimọ-the-bible-in-yoruba.apk arquivo em seu telefone em 4 passos simples:
Sim. Fornecemos alguns dos espelhos de download do Apk mais seguros para obter o apk Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba).
A versão mais recente do Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) é a versão 1.2 e foi atualizada pela última vez 2 months ago. Eleyi jẹ Bibeli ni Yorùbá ni pipe pẹlu gbogbo awọn iwe ohun, orí ati awọn ẹsẹ.. A ti fi ọpọlọpọ awọn ẹya ohun mere mere lati jẹki kika ati iwadi ti Bibeli re gbẹgẹ. Wa’di O le lo ohun elo iwa’di iṣẹ lati wa ẹsẹ Bibeli lori ero kan pato. Kọ rọra tẹ ọrọ ti ohun wa ki ‘app’ si gbe ẹsẹ ti o jẹmọ jade si ọ. Fi awọn ẹsẹ han lori Facebook, Twitter ati Email Ni bayi o le fi ẹsẹ lati nu Bibeli han awọn ọrẹ rẹ taara lori Facebook, Twitter tabi nipasẹ Email (ki o si fi erongba ọkan rẹ han). Kọ Adura ati awon ero Ọpọlọpọ awọn ti nlo ate eto wa n beere fun ohun ti wọn le lo lati le kọ awọn àdúrà wọn, ero tabi oro ti won gba nigbati wọn ba n ka Bibeli wọn. Ṣẹda adura arare ati ero re, fi wọn pamọ sinu awọn ‘app’ ati paapa fi wọn han si awọn ọrẹ rẹ lori Facebook, Twitter tabi nipasẹ email Isaami si ẹsẹ Nibayi o le saami ti o yatọ si awon ẹsẹ bibeli pelu awọn awọ ti o ba wu ọ. kọ rọra tẹ aworan geege nigba ti o ba n ka ọrọ Bibeli lọwọ Bayi o le ri ese ti o yatọ ninu àwo ti o fẹ. Ko tẹ awọn aami ohun elo ikọwe bi o ba ka awọn ọrọ Bibeli Bukumaaki Bukumaaki yio ran ọ lọwọ lati sami si ibi tire ninu ọrọ bibeli. Awọn aami bukumaaki yi ni owa loke iboju. kọ fi ika tọ lati sami sori rẹ. Nigba ti o ba pada si ‘app’ tẹ aami ti owa loke ti iboju, yio si gbe ọ lọ sibi ti o ti kuro. Wa ki o si se afiwe awọn ẹsẹ (Ni App) Awọn ‘app’ yi ni o ni "iboju wẹẹrẹ" ti o jẹ ki o sese fun o lati wo ẹsẹ meji ni akoko kan na ati ki o le ka ki o si ṣe afiwe wọn l’ẹgbẹ ara won. Ọpa Ìkẹkọọ - Išė Akojọ Ṣẹda awọn iwe aṣẹ eleyọ tabi olọpọ ẹsẹ. Fi iwadi rẹ si ẹgbẹẹ àwọn ẹsẹ ọun. O le se ifiwe ran se (email) awọn iwe aṣẹ lati nu ‘app’. Eda King James ni ede oyibo Ka bibeli ti eda King James ni ede oyibo. Se afiwe awon ẹsẹ kankan lati nu eda ti Swedish pelu tie de oyibo. Pe Wa A n reti awọn esi rẹ. A ma n gbọ a si tun mu awọn ohun titun sinu ‘app’ na nipase awon arọwa yin. O le fi iwe ranṣẹ si wa nipasẹ awọn olubasọrọ wa ninu iṣẹ ‘app’ yi.. Baixe o aplicativo em 54.11 MB agora. Se você gostou de Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba), você vai gostar de Book apps como Yoruba Bible - Bibeli Mimo; KJV Bible / AcroBible Suite; The Scriptures; RVA Spanish Bible (Biblia Español);
Espelho 1: : Baixar APK
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|